Skip to main content

Posts

Showing posts from January, 2014

EarnStart is fake!

I think this guys are not real and genuine so far, no one in this region that I know have been able to receive payment. Hello guys check this site out they promise one can make cool cash just by helping them to generate traffic http://2cashsite.com/?id=117748 They just confirmed that they are fake, they have deleted my account. And I think they are really scared. Lol!

What a Special Day!

Ogo oluwa ti fi ara ran ninu aye re Orire ni ti re ibukun oluwa yo wa pelu re loke loke lo malo emi oluwa  ma ma gbe ninu re O ti se aseyori ibukun lo je fun awon olu gbagbe re anu oluwa yo ma ba o gbe adun oluwa yo wa opolopo Oluwa  ti gbe o soke Oluwa ti segun  fun re alaafia to pe ye ni olorun ti fun re olorun yo to ina re lati oke si inu aye re idi oruko re yo fi ara han O fun orile-ede re ni oro nipasẹ re orile-ede re yo tayo Ayobami lo ru ko re ayo yo ba re Oluwa seun nipase re gbo araye yo so pe oluwa Seun Oluwa Gbemileke oluwa agbe orile-ede re soke ni pa re Temitope ayo re yo kun akun wa sile Ayilara (Ayi ni nu ara) O' gbadun ojurere ni awujo Ni oruko Jesu ni mo gba adura  (amin)