Orire ni ti re
ibukun oluwa yo wa pelu re
loke loke lo malo
emi oluwa ma ma gbe ninu re
O ti se aseyori
ibukun lo je fun awon olu gbagbe re
anu oluwa yo ma ba o gbe
adun oluwa yo wa opolopo
Oluwa ti gbe o soke
Oluwa ti segun fun re
alaafia to pe ye ni olorun ti fun re
olorun yo to ina re lati oke si inu aye re
idi oruko re yo fi ara han
O fun orile-ede re ni oro
nipasẹ re orile-ede re yo tayo
Ayobami lo ru ko re ayo yo ba re
Oluwa seun nipase re gbo araye yo so pe oluwa Seun
Oluwa Gbemileke oluwa agbe orile-ede re soke ni pa re
Temitope ayo re yo kun akun wa sile
Ayilara (Ayi ni nu ara) O' gbadun ojurere ni awujo
Ni oruko Jesu ni mo gba adura (amin)
Comments
Post a Comment